Yoruba Hymn APA 587 - Olugbala gbohun mi

Yoruba Hymn APA 587 - Olugbala gbohun mi

Yoruba Hymn  APA 587 - Olugbala gbohun mi

APA 5871. Olugbala gbohun mi,

Gbohun mi, gbohun mi;

Mo wa sodo Re, gba mi,

Nibi agbelebu.

Emi se, sugbon, O ku;

Iwo ku, Iwo ku;

Fi anu Re pa mi mo.

Nibi agbelebu.

Oluwa, jo gba mi,

Nk’ y’o bi O ninu mo!

Alabukun, gba mi,

Nibi agbelebu.
2. Bi ngo ba tile segbe,

Ngo bebe! ngo bebe!

Iwo li ona iye,

Nibi agbelebu.

Ore-ofe Re t’ a gba,

Lofe ni! lofe ni!

F’oju anu Re wo mi,

Nibi agbelebu.

Oluwa jo, &c.
3. F’ eje mimo Re we mi,

Fi we mi! fi we mi!

Ri mi sinu ibu re,

Nibi agbelebu.

’Gbagbo l’o le fun wa ni

’Dariji ! ’Dariji !

Mo f’ igbagbo ro mo O,

Nibi agbelebu.

Oluwa jo, &c. Amin.


 Yoruba Hymn  APA 587 - Olugbala gbohun mi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 587- Olugbala gbohun mi. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post