Yoruba Anglican Hymn apa 10 - Baba mi gbo temi

Yoruba Anglican Hymn apa 10 - Baba mi gbo temi

Yoruba Hymn Apa 10 - Baba mi gbo temi

APA 10

1. Baba mi gbo temi !

 ’Wo ni alabo mi,

 Ma sunmo mi titi:

 Oninure julo !

 

2. Jesu Oluwa mi,

 Iye at’ ogo mi,

 K’ igba na yara de,

 Ti ngo de odo Re.


3. Olutunu julo,

 ’Wo ti ngbe inu mi,

 ’Wo t’ o mo aini mi,

 Fa mi, k’ o si gba mi.


4. Mimo, mimo, mimo,

 Ma fi mi sile lai;

 Se mi n’ ibugbe Re,

 Tire nikan lailai. Amin.


This is Yoruba Anglican hymns, APA 10 - Mo ji, mo ji, ogun orun. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post