Yoruba Anglican Hymn Apa 15 - Wa ba mi gbe! ale fere le tan

Yoruba Anglican Hymn Apa 15 - Wa ba mi gbe! ale fere le tan

Yoruba Hymn Apa 15 - Wa ba mi gbe! ale fere le tan

APA 15

1. Wa ba mi gbe ! ale fere le tan,

 Okunkun nsu; Oluwa ba mi gbe,

 Bi oluranlowo miran ba ye,

 Iranwo alaini, wa ba mi gbe !


2. Ojo aiye mi nsare lo s’opin,

 Ayo aiye nku, ogo re nwomi;

 Ayida at’ ibaje ni mo nri;

 ’Wo ti ki yipada wa ba mi gbe.


3. Ma wa l’ eru b’ Oba awon oba,

 Sugbon ki o ma bo b’oninure;

 Ki o si ma kanu fun egbe mi;

 Wa, Ore elese, wa ba mi gbe !


4. Mo nfe O ri, ni wakati gbogbo:

 Ki l’ o le segun Esu b’ ore Re?

 Tal’ o le se amona mi bi Re?

 N’nu ’banuje at’ ayo, ba mi gbe !


5. Pelu’ bukun Re, eru ko ba mi:

 Ibi ko wuwo, ekun ko koro;

 Oro iku da? ’segun isa da?

 Ngo segun sibe, b’ Iwo ba mi gbe.


6. Wa ba mi gbe ni wakati iku,

 Se ’mole mi, si toka si orun:

 B’ aiye ti nkoja, k’ile orun mo,

 Ni yiye, ni kiku, wa ba mi gbe. Amin.This is Yoruba Anglican hymns, Yoruba Hymn Apa 15 - Wa ba mi gbe! ale fere le tan. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post