Yoruba Anglican Hymn APA 9 - Jesu, Orun ododo

Yoruba Anglican Hymn APA 9 - Jesu, Orun ododo

Yoruba Hymn APA 9 - Jesu, Orun ododo

APA 9

1. Jesu, Orun ododo,

 Iwo imolfe ife;

 Gbat’ imole owuro

 Ba nt’ ila orun tan wa,

 Tanmole ododo Re

 Yi wa ka.


 2. Gege bi iri tin se

 Sori eweko gbogbo,

 K’ Emi ore-ofe Re

 So okan wa di otun;

 Ro ojo ibukun Re

 Sori wa.


3. B’ imole orun tin ran,

 K’ imole ife Tire,

 Si ma gbona l’okan wa;

 K’o si mu wa l’ara ya,

 K’a le ma f’ayo sin O

 L’aiye wa.


4. Amona, Ireti wa,

 Ma fi wa sile titi;

 Fi wa sabe iso Re

 Titi opine mi wa,

 Sin wa la ajo wa ja

 S’ ile wa.

 

5. Pa wa mo n’nu ife Re

 Lojo aiye wa gbogbo,

 Si mu wa bori iku,

 Mu wa de ‘le ayo na,

 K’a le b’ awon mimo gba

 Isimi. Amin.This is Yoruba Anglican Hymn APA 9 - Jesu, Orun ododo. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post