Yoruba Hymn APA 21 - K’ a to sun, Olugba wa

  Yoruba Hymn  APA 21 - K’ a to sun, Olugba wa

APA 21

1. K’ a to sun, Olugba wa,

 Fun wa n’ ibukun ale;

 A jewo ese wa fun O,

 Iwo l’ o le gba wa la.


2. B’ ile tile ti sududu,

 Okun ko le se wa mo;

 Iwo eniti ki sare

 Nso awon enia Re.


3. B’ iparun tile yi wa ka,

 Ti ofa nfo wa koja,

 Awon angeli yio wa ka,

 Awa o wa l’ ailewu.


4. Sugbo b’ iku ba ji wa pa,

 Ti ’busun wa d’ iboji,

 Je k’ ile mo wa sodo Re

 L’ ayo at’ Alafia.


5. N’ irele awa f’ ara wa

 Sabe abo Re, Baba;

 Jesu, ’ Wo t’ o sun bi awa,

 Se orun wa bi Tire.

 

6. Emi Mimo, rado bow a,

 Tan ’mole s’ okunkun wa

 Tit’ awa o fi ri ojo

 Imole aiyeraiye. Amin. Yoruba Hymn  APA 21 - K’ a to sun, Olugba wa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 21 - K’ a to sun, Olugba wa. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post