Yoruba Anglican Hymn APA 22 - Jesu, bukun wa k’ a to lo

Yoruba Anglican Hymn APA 22 - Jesu, bukun wa k’ a to lo

 Yoruba Hymn  APA 22 - Jesu, bukun wa k’ a to lo

APA 22

 1. Jesu, bukun wa k’ a to lo:

 Gbin oro Re si aiya wa;

 K’o si mu k’ ife gbigbona

 Kun okan ilowowo wa;

 Nigba iye at’ iku wa,

 Jesu, jare, se ’mole wa.


2. Ile ti su, orun ti wo;

 ’Wo si ti siro iwa wa;

 Die n’ isegun wa loni

 Isubu wa l’o papoju:

 Nigba iye ati, &c.


3. Jesu, dariji wa: fun wa

 L’ ayo, ati eru mimo,

 At’ okan ti ko l’ abawon

 K’ a ba le jo O l’ ajotan:

 Nigba iye ati, &c.


4. Lala dun, ’tor’ Iwo se ri;

 Aniyan fere, O se ri;

 Ma je k’ a gbo t’ ara nikan

 K’ a ma bo sinu idewo.

 Nigba iye ati, &c.


5. A mbe O f’ awon alaini,

 F’ elese at’ awon t’ a fe;

 Je ki anu Re mu wa yo,

 ’Wo Jesu, l’ ohun gbogbo wa.

 Nigba iye ati, &c.

 

6. Jesu, bukun wa, - ile su;

 Tikalare wa ba wag be:

 Angel’ rere nso ile wa;

 A tun f’ ojo kan sunmo O.

 Nigba iye ati, &c. Amin.Yoruba Hymn  APA 22 - Jesu, bukun wa k’ a to lo

This is Yoruba Anglican hymns, APA 22 - Jesu, bukun wa k’ a to lo. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post