Yoruba Hymn APA 38 - K’ ojo ’simi yi to tan
APA 38
1. K’ ojo ’simi yi to tan,
k’a to lo f’ ara le ’le
A wa wole lese Re
A nkorin iyin si O.
2. Fun anu ojo oni
Fun isimi lona wa,
’Wo nikan l’a f’ ope fun
Oluwa at’ Oba wa.
3. Isin wa ko nilari,
Adura wa lu m’ ese;
Sugbon, ’Wo l’o nf’ ese ji,
Or-ofe Re to fun wa.
4. Je k’ ife Re ma to wa
B’a ti nrin ’na aiye yi;
Nigbat’ ajo wa ba pin,
K’a le simi lodo Re.
5. K’ ojo ’simi wonyi je
Ibere ayo orun;
B’ a ti nrin ajo wa lo
S’ isimi ti ko l’ opin. Amin.
This is Yoruba Anglican hymns, APA 38 - K’ ojo ’simi yi to tan. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.