Yoruba Hymn APA 39 - Emi Olorun alaye

Yoruba Hymn APA 39 - Emi Olorun alaye

  Yoruba Hymn  APA  39 - Emi Olorun alaye

APA 39

1. Emi Olorun alaye,

 N’nu ekun ore-ofe Re,

 Nibiti’ ese enia ti te,

 Sokale sori iran wa.


2. F’ebun ahon, okan ife,

 Fun wa lati soro ’fe Re,

 K’ibukun at’agbara Re,

 Ba l’awon t’o ngbo oro na.


3. K’okun kase ni bibo Re:

 Ki darudapo di tito;

 F’ilera f’okan ailera;

 Je ki anu bori ’binu.


4. Emi Olorun, jo pese

 Gbogbo aiye fun Oluwa;

 Mi si won b’afefe oro,

 K’ okan okuta le soji.

 

5. Baptis’ gbogb’ orile-ede;

 Rohin ’segun Jesu yika;

 Yin oruko Jesu logo

 Tit’ araiye yio jewo Re. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 39 - Emi Olorun alaye. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post