Yoruba Hymn APA 42 - Oluwa ’kore. ’Wo l’a nyin

Yoruba Hymn APA 42 - Oluwa ’kore. ’Wo l’a nyin

 Yoruba Hymn  APA 42 - Oluwa ’kore. ’Wo l’a nyin

APA 42

 1. Oluwa ’kore. ’Wo l’a nyin;

 Ileri Re ’gbani ko ye;

 Orisi igba si nyipo,

 Ododun kun fun ore Re;

 Lojo oni, awa dupe;

 Je k’ iyin gba okan wa kan.


2. B’ akoko ’rugbin mu way o;

 B’ igba erun nmu oru wa;

 ’Gbat’ owo ojo ba nrinle;

 Tabi’ igbat’ ikore bap on,

 ’Wo Oba wa l’a o ma yin;

 ’Wo l’ alakoso gbogbo won.


3. Ju gbogbo re lo, nigbati

 Owo Re fun opo ka ’le;

 Gbat’ ohun ayo gbilekan,

 B’ eda ti nko ire won jo;

 Awa pelu y’o ma yin O

 Ore Re ni gbogbo wan pin.

 

4. Oluwa ’Kore, Tire ni

 Ojo ti nro, orun tin ran:

 Irugbin ti a gbin sile,

 Tire l’ ogbon tin mu dagba:

 Otun lebun Re l’ ododun;

 Otun n’iyin Re l’ enu wa. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 42 - Oluwa ’kore. ’Wo l’a nyin. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.


Post a Comment (0)
Previous Post Next Post