Yoruba Anglican Hymn APA 3 - Nigbat’ imole owuro

Yoruba Anglican Hymn APA 3 - Nigbat’ imole owuro

Yoruba Hymn APA 3 - Nigbat’ imole owuro

APA 3

1. Nigbat’ imole owuro

 B anti ila orun tan wa,

 A! Orun ododo mimo

 Ma sai fi anu ran si mi !

 Tu isudede ebi ka

 S’ okunkun mi d’ imole nla.


2. ’Gbati mba m’ ebo oro wa

 ’Waju Olorun t’ o logo

 Olugbala, ti mba nkanu

 Nitori ese ti mo da,

Jesu ! fie je Re we mi,

Ma sai se alagbawi mi.


3. ’Gba gbogbo ise ojo pin,

 Ti ara si nfe lo simi,

 F’ anu t’ o kun fun ’dariji,

 Dabobo mi, Oluwa mi;

 Bi orun si ti ’ma goke,

 Beni k’ o gb’ ero mi soke.

 

4. ’Gbat’ orun aiye mi ba wo,

 Ti ko si si wahala mo,

 Je k’ imole tire, Jesu !

 Tan boji ti mo sun yika;

 Gb’ emi mi dide, Oluwa,

 Ki nri O, ki nsi gbe O ga. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, Yoruba Anglican Hymn Apa 3 - Nigbat’ imole owuro. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post