Yoruba Anglican Hymn APA 4 - Oluwa mi, mo njade lo

Yoruba Anglican Hymn APA 4 - Oluwa mi, mo njade lo

 Yoruba Hymn APA  4 - Oluwa mi, mo njade lo

APA 4

 1. Oluwa mi, mo njade lo,

 Lati se ise ojo mi;

 Iwo nikanl’ emi o mo,

 L’ oro, l’ ero, ati n’ ise.

 

2. Ise t’ o yan mi, l’ anu Re,

 Je ki nle se tayotayo;

 Ki nr’ oju Re ni ise mi,

 K’ emi si le f’ ife Re han.

 

3. Dabobo mi lowo ‘danwo,

 K’ o pa okan mi mo kuro

 L’ owo aniyan aiye yi,

 Ati gbogbo ifekufe.

 

 4. Iwo t’olju Re r’ okan mi,

 Ma wa low’ otun mi titi,

 Ki mma sise lo l’ ase Re,

 Ki nf’ ise mi gbogbo fun O.

 

5. Je ki nreru Re t’o fuye,

 Ki mma sora nigbagbogbo;

 Ki mma f’ oju si nkan t’ orun,

 Ki nsi mura d’ ojo ogo.

 

6. Ohunkohun t’o fi fun mi

 Je kin le lo fun ogo Re:

 Ki nfayo sure ije mi;

 Ki mba O rin titi d’ orun. Amin.This is Yoruba Anglican hymns,  Yoruba Anglican Hymn Apa  4 - Oluwa mi, mo njade lo. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post