Yoruba Anglican Hymn Apa 5 - Wa s’odo mi, Oluwa mi

Yoruba Anglican Hymn Apa 5 - Wa s’odo mi, Oluwa mi

Yoruba Hymn Apa 5 - Wa s’odo mi, Oluwa mi

APA 5

1. Wa s’odo mi, Oluwa mi,

 Ni kutukutu owuro;

 Mu k’ ero rere so jade,

 Lat’ inu mi soke orun.


2. Wa s’odo mi Oluwa mi,

 Ni wakati osan gangan;

 Ki ’yonu ma ba se mi mo

 Nwon a si s’ osan mi d’ oru.


3. Wa s’odo mi Oluwa mi,

 Nigbati ale ban le lo;

 Bi okan mi ba nsako lo,

 Mu pada; f’oju ’re wo mi.


4. Wa s’odo mi Oluwa mi,

 Li oru, nigbati orun

 Ko woju mi; je k’okan mi

 Ri ’simi je li aiya Re.


5. Wa s’odo mi, Oluwa mi

 Ni gbogbo ojo aiye mi;

 Nigbati emi mi ba pin,

 Kin le n’ ibugbe lodo Re. Amin.


This is Yoruba Anglican hymns, Yoruba Anglican Hymn Apa  5 - Wa s’odo mi, Oluwa mi  Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post