Yoruba Anglican Hymn APA 6 - Krist, Ologo, Olola

Yoruba Anglican Hymn APA 6 - Krist, Ologo, Olola

Yoruba Hymn Apa 6 - Krist, Ologo, Olola

APA 6

1. Krist, Ologo, Olola,

Iwo imole aiye,

Orun ododo, dide,

K’ o si bori okunkun;

‘Mole oro, sunmo mi,

‘Rawo oro, w’aiya mi.


2. Okunkun l’owuro je

B’ Iwo ko pelu re wa;

Ailayo l’ojo yi je,

B’ anu ko tan mole mi,

Fun mi n’ imole, Jesu,

M’okan mi gbogbo gbona.


3. Wa be okan mi yi wo,

Le okunkun ese lo:

F’ imole orun kun mi,

Si tu aigbagbo mi ka,

Ma f’ara Re han mi si,

Si ma ran b’ osangangan. Amin.This is Yoruba Anglican hymns, Yoruba Hymn Apa 6 - Krist, Ologo, Olola Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post