Yoruba Anglican Hymn Apa 7 - Wa s’ adura oro

Yoruba Anglican Hymn Apa 7 - Wa s’ adura oro

Yoruba Hymn APA 7 - Wa s’ adura oro

APA 7

 1. Wa s’ adura oro,

 Kunle k’ a gbadura;

 Adura ni opa Kristian,

 Lati b’ Olorun rin.

 

2. Losan, wole labe

 Apat’ aiyeraiye;

 Itura ojiji Re dun

 Nigbat’ orun ba mu.


3. Je ki gbogbo ile

 Wa gbadura l’ ale

 Ki ile wa di t’ Olorun

 Ati ’bode orun.


4. Nigbat’ o d’ oganjo,

 Je k’ a wi l’ emi pe

 Mo sun, sugbon okan mi ji

 Lati ba O sona. Amin.This is Yoruba Anglican hymns,  Apa 7 - Wa s’ adura oro. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.
Post a Comment (0)
Previous Post Next Post