Yoruba Hymn APA 108 - Bi ’gba ti Mose gbe ejo

Yoruba Hymn APA 108 - Bi ’gba ti Mose gbe ejo

 Yoruba Hymn  APA 108 - Bi ’gba ti Mose gbe ejo

APA 108

1. Bi ’gba ti Mose gbe ejo

 S’ oke li aginju,

 Awon ti ejo san, nwon san;

 Nwon dekun lati ku.


2. Beni lati odo Jesu

 N’ imularada nde;

 Eni t’ o si f’ igbagbo wo

 Yio si ri ’gbala.


3. O wa lati gbe wa dide,

 Lati fun wa n’ iye,

 Igbagbo mu wa sunmo O

 K’ a ma se foya mo. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 108 - Bi ’gba ti Mose gbe ejo  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post