Yoruba Hymn APA 107 - E funpe na kikan

Yoruba Hymn APA 107 - E funpe na kikan

 Yoruba Hymn  APA 107 - E funpe na kikan

APA 107

1. E funpe na kikan,

 Ipe ihinrere;

 K’ o dun jake jado

 L’ eti gbogbo eda;

 Odun idasile ti de;

 Pada elese, e pada.


2. Fun ’pe t’ Odagutan

 T’ a ti pa s’ etutu;

 Je ki agbaiye mo

 Agbara eje Re.

 Odun idasile, &c.


3. Enyin eru ese,

 E so ’ra nyin d’ omo,

 Lowo Kristi Jesu

 E gba ominira nyin.

 Odun idasile, &c.


4. Olori Alufa

 L’ Olugbala ise;

 O fi ’ra Re rubo

 Arukun, aruda.

 Odun idasile, &c.


5. Okan alare, wa,

 Simi lara Jesu:

 Onirobinuje

 Tujuka, si ma yo.

 Odun idasile, &c. Amin.

This is Yoruba Anglican hymns, APA 107 - E funpe na kikan  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post