Yoruba Hymn APA 124 - Ilu t’ o dara po l’ aiye
APA 124
1. Ilu t’ o dara po l’ aiye;
Betlehem, ’wo ta won yo;
Ninu re l’ Oluwa ti wa
Lati joba Israel.
2. Ogo ti irawo ni ju
Ti orun owuro lo;
Irawo t’ o kede Jesu
Ti a bi ninu ara.
3. Awon ’logbon ila-orun
Mu ’yebiye ore wa;
E wo, bi nwon ti fi wura,
Turari, ojia fun.
4. Jesu, ’Wo ti keferi nsin
Li ojo ifihan Re;
Fun O, Baba l’ a f’ ogo fun,
Ati fun Emi Mimo. Amin.
This is Yoruba Anglican hymns, APA 124 - Ilu t’ o dara po l’ aiye . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwo orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.