Yoruba Hymn APA 232 - Jesu ore elese ku

Yoruba Hymn APA 232 - Jesu ore elese ku

Yoruba Hymn  APA 232 - Jesu ore elese ku

APA 232

 1. Jesu ore elese ku,

 Awon omo Salem nsokun:

 Okunkun bo oju orun,

 Isele nla se lojiji.


2. Nihin l’ a r’ anu at’ ife,

 Oba ogo ku f’ enia;

 Wo! ayo ki l’ a tun ri yi,

 Jesu t’ O ku tun ji dide.


3. Ma beru mo, enyin mimo;

 So bi Oluwa ti joba;

 Korin b’ O ti segun Esu,

 Bi O si ti bori iku.


4. E wipe, “Oba, wa titi,

 Iwo t’ a bi lati gba wa;”

 K’ e b’ iku pe, “Oro re da?”

 “Iboji, isegun re da?” Amin.


Yoruba Hymn  APA 232 - Jesu ore elese ku


This is Yoruba Anglican hymns, APA 232-  Jesu ore elese ku  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post