Yoruba Hymn APA 252 - Olor’ Alufa giga kan

Yoruba Hymn APA 252 - Olor’ Alufa giga kan

 Yoruba Hymn  APA 252 -  Olor’ Alufa giga kan

APA 252

1. Olor’ Alufa giga kan,

 To gb’eda wa wo farahan,

 Nibiti tempil’ orun wa,

 Ile Olorun t’a ko ko.


2. On, bi Onigbowo enia,

 To t’eje ’yebiye s’ile,

 To npari ’se nla Re l’orun,

 Olugbala, Ore enia.


3. B’ o tile goke lo s’orun,

 O nfoju ife wo aiye,

 Enit’ o nje oko enia,

 O mo ailera eda wa.


4. Alabajiya wa si mo

 Bi ’rora wa si tip o to;

 L’orun, o si nranti sibe,

 Omije on ’waiya ja Re.


5. Ninu ibanuje okan,

 Eni ’Banuje pin n’nu re;

 O mba wa daro edun wa,

 O sin ran ojiya lowo.


6. K’ a k’edun wa lo sodo Re,

 Pelu ’gboiya, nibi ite;

 K’a toro agbara orun,

 Lati yow a nigba ibi. Amin.


 Yoruba Hymn  APA 252 -  Olor’ Alufa giga kan

This is Yoruba Anglican hymns, APA 252- Olor’ Alufa giga kan   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post