Yoruba Hymn APA 256 - Ile ayo kan wa

Yoruba Hymn APA 256 - Ile ayo kan wa

Yoruba Hymn  APA 256 - Ile ayo kan wa

APA 256

 1. Ile ayo kan wa

 Ti o jina,

 Ni b’ awon mimo wa:

 Nwon nran b’ orun;

 A! nwon nkorin didun,

 Yiye, l’ Olugbala wa:

 Ki iyin Re k’ o ro,

 Yin yin lailai.


2. Wa sile ayo yi,

 Wa, wa k’ a lo;

 E se nsiyemeji?

 E se nduro?

 Ao wa l’alafia,

 Kuro l’ ese at’ aro:

 A o ba o joba,

 L’ayo lailai.


3. Oju gbogbo won ndan,

 N’ ile ayo;

 N’ ipamo Baba wa,

 Ife ki ’ku;

 Nje sure lo s’ ogo,

 Gba ade at’ ijoba;

 T’ o mo ju orun lo,

 Joba titi. Amin.Yoruba Hymn  APA 256 - Ile ayo kan wa


This is Yoruba Anglican hymns, APA 256- Ile ayo kan wa  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post