Yoruba Hymn APA 266 - Emi Olorun mi

Yoruba Hymn APA 266 - Emi Olorun mi

Yoruba Hymn  APA 266 - Emi Olorun mi

APA 266

 1. Emi Olorun mi,

 L’ojo ’tewogba yi;

 Gege b’ ojo Pentikosti,

 Sokale l’ agbara.

 Lokan kan l’ a pade

 Ninu ile Re yi;

 A duro de ileri Re,

 A duro de Emi.


2. B’ iro iji lile,

 Wa kun ’nu ile yi;

 Mi Emi isokan si wa,

 Okan kan, imo kan.

 Fun ewe at’ agba

 L’ ogbon at’ oke wa;

 Fi okan gbigbona fun wa:

 K’a yin, k’a gbadura.


3. Emi imole, wa

 Le okunkun jade;

 Siwaju ni k’ imole tan

 Titi d’osangangan.

 Emi otito wa,

 S’amona wa titi;

 Emi Isodomo, si wa

 S’okan wa di mimo Amin.


Yoruba Hymn  APA 266 - Emi Olorun mi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 266-  Emi Olorun mi   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post