Yoruba Hymn APA 265 - Gbani t’ Olorun sokale

Yoruba Hymn APA 265 - Gbani t’ Olorun sokale

 Yoruba Hymn  APA 265 - Gbani t’ Olorun sokale

APA 265

1. ‘Gbani t’ Olorun sokale,

 O wa ni ibinu;

 Ara sin san niwaju Re,

 Okunkun on ina.


2. Nigbati’ o wa nigba keji,

 O wa ninu ife;

 Emi Re si ntu ni lara,

 B’ afefe owuro.


3. Ina Sinai ijo kini,

 T’ owo re mbu soke,

 Sokale jeje bi ade,

 Si ori gbogbo won.


4. Bi ohun eru na ti dun,

 L’eti Israeli,

 Ti nwon si gbo iro ipe,

 To m’ ohun angeli gbon.


5. Be gege nigbat’ Emi wa

 Ba le awon Tire,

 Iro kan si ti orun wa,

 Iro iji lile.


6. O nkun Ijo Jesu, o nkun

 Aiye ese yika;

 L’okan alaigboran nikan

 Ni aye ko si fun.


7. Wa, Ogbo, Ife, at’ Ipa,

 Mu ki eti wa si;

 K’a ma so akoko wa nu;

 Ki ‘fe Re le gba wa. Amin.


Yoruba Hymn  APA 265 - Gbani t’ Olorun sokale


This is Yoruba Anglican hymns, APA 265- Gbani t’ Olorun sokale  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post