Yoruba Hymn APA 269 - Emi Mimo sokale

Yoruba Hymn APA 269 - Emi Mimo sokale

 Yoruba Hymn  APA 269 - Emi Mimo sokale

APA 269

1. Emi Mimo sokale,

 Fi ohun orun han;

 K’ o mu imole w’ aiye,

 Si ara enia.

 K’ awa t’ a wa l’ okunkun,

 Ki o le ma reran,

 ’Tori Jesu Kristi ku

 Fun gbogbo enia.


2. K’ o fi han pe elese

 Ni emi nse papa;

 K’ emi k’ o le gbeke mi

 Le Olugbala mi.

 Nigbati a we mi nu

 Kuro ninu ese,

 Emi o le fi ogo

 Fun Eni-mimo na.


3. K’ o mu mi se aferi

 Lati to Jesu lo;

 K’o joba ni okan mi,

 K’o so mi di mimo;

 Ki ara ati okan,

 K’ o dapo lati sin

 Olorun Eni-mimo,

 Metalokansoso. Amin.Yoruba Hymn  APA 269 - Emi Mimo sokale

This is Yoruba Anglican hymns, APA 269-   Emi Mimo sokale   . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post