Yoruba Hymn APA 270 - Adaba orun, sokale

Yoruba Hymn APA 270 - Adaba orun, sokale

 Yoruba Hymn  APA 270 - Adaba orun, sokale

APA 270

1. Adaba orun, sokale,

 Gbe wa lo l’ apa iye Re;

 Ki o sig be wa ga soke,

 Ju gbogbo ohun aiye lo.


2. Awa iba le ri ite

 Olodumare Baba wa,

 Olugbala joko nibe,

 O gunwa l’ awo bi tiwa.


3. Egbe mimo duro yi ka,

 Ite, Agbara wole fun,

 Olorun han ninu ara,

 O si tan ogo yi won ka.


4. Oluwa, akoko wo ni

 Emi o de bugbe loke?

 T’ emi o ma ba won wole,

 Kim ma sin O, ki mma korin? Amin.Yoruba Hymn  APA 270 - Adaba orun, sokale

This is Yoruba Anglican hymns, APA 270-   Adaba orun, sokale  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post