Yoruba Hymn APA 272 - Wa, Parakliti mimo

Yoruba Hymn APA 272 - Wa, Parakliti mimo

 Yoruba Hymn  APA 272 - Wa, Parakliti mimo

APA 272

1. Wa, Parakliti mimo,

 Lat’ ibugbe Re orun,

 Ran itansan ’mole wa.


2. Baba talaka, wa ’hin,

 Olufunni l’ebun, wa,

 Imole okan, jo wa.


3. Baba olutunu, wa,

 Alejo toto f’okan,

 Pelu itura Re, wa.


4. Wo n’ isimi n’nu lala,

 Iboji ninu oru,

 Itunu ninu ’ponju.


5. ’Wo ’mole t’o mo gara,

 Tan sinu aiya awon

 Enia Re oloto.


6. Laisi Re, kil’ eda je?

 Ise at’ ero mimo,

 Lat’ odo Re wa ni nwon.


7. Eleri, so di mimo,

 Agbogbe, ma sai wo san,

 Alaileso, mu s’ eso.


8. Mu okan tutu gbona,

 M’ alagidi teriba,

 Fa asako wa jeje.


9. F’Emi ’jinle Re meje,

 Kun awon oloto Re,

 F’agbara Re s’abo won.


10. Ran or’-ofe Re sihin,

 Ekun igbala l’aiye,

 At’ Alafia l’orun. Amin.Yoruba Hymn  APA 272 - Wa, Parakliti mimo

This is Yoruba Anglican hymns, APA 272 - Wa, Parakliti mimo  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post