Yoruba Hymn APA 271 - Emi anu, oto, ife

Yoruba Hymn APA 271 - Emi anu, oto, ife

 Yoruba Hymn  APA 271 - Emi anu, oto, ife

APA 271

1. Emi anu, oto, ife,

 Ran agbara Re t’ oke wa;

 Mu iyanu ojo oni,

 De opin akoko gbogbo.


2. Ki gbogbo orile ede,

 Ko orin ogo Olorun;

 Ki a si ko gbogbo aiye,

 N’ ise Olurapada wa.


3. Olutunu at’ Amona,

 Joba ijo enia Re,

 K’ araiye mo ibukun Re,

 Emi anu, oto, ife. Amin.Yoruba Hymn  APA 271 - Emi anu, oto, ife

This is Yoruba Anglican hymns, APA 271- Emi anu, oto, ife  . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post