Yoruba Hymn APA 385 - Gbekele Olorun re

Yoruba Hymn APA 385 - Gbekele Olorun re

 Yoruba Hymn  APA 385 - Gbekele Olorun re

APA 385

1. Gbekele Olorun re,

 K’o ma nso! K’o ma nso!

 D’ileri Re mu sinsin,

 K’ o ma nso!

 Mase se oruko Re,

 B’o tile mu egan wa;

 Ma tan ihin Re kale;

 Si ma nso!


2. O ti pe o s’ise Re?

 Sa ma nso! Sa ma nso!

 Orumbo, mura sin!

 Sa ma nso!

 Sin n’ ife at’ igbagbo;

 Gbekele agbara Re;

 Fi ori ti de opin;

 Sa ma nso!


3. O ti fun o ni ‘rugbin?

 Sa ma nso! Sa ma nso!

 Ma gbin, ‘wo o tun kore!

 Sa ma nso!

 Ma sora, si ma reti

 L’enu ona Oluwa;

 Y’o dahun adura re;

 Sa ma nso!


4. O ti wipe opin mbo?

 Sa ma nso! Sa ma nso!

 Nje fi eru mimo sin!

 Sa ma nso!

 Kristi l’ atilehin re,

 On na si ni onje re,

 Y’o sin o de ‘nu ogo.

 Sa ma nso!


5. Ni akoo die yi;

 Sa ma nso! Sa ma nso!

 Jewo Re ni ona re:

 Si ma nso!

 Ka ri okan Re n’nu re

 K’ ife Re je ayo re

 L’ ojo aiye re gbogbo,

 Si ma nso! Amin. Yoruba Hymn  APA 385 - Gbekele Olorun re

This is Yoruba Anglican hymns, APA 385- Gbekele Olorun re. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post