Yoruba Hymn APA 384 - Gba aiye mi, Oluwa

Yoruba Hymn APA 384 - Gba aiye mi, Oluwa

 Yoruba Hymn  APA 384 - Gba aiye mi, Oluwa

APA 384

1. Gba aiye mi, Oluwa,

 Mo ya si mimo fun O;

 Gba gbogbo akoko mi,

 Ki won kun fun iyin Re.


2. Gba owo mi, k’O si je

 Ki nma lo fun ife Re.

 Gba ese mi, k’ O si je

 Ki nwon ma sare fun O.


3. Gba ohun mi, je ki nma

 Korin f’ Oba mi titi;

 Gba ete mi, je kin won

 Ma jise fun O titi;


4. Gba wura, fadaka mi,

 Okan nki o da duro;

 Gba ogbon mi, k’O sil lo,

 Gege bi O ba ti fe.


5. Gba ‘fe mi, fi se Tire;

 Ki o tun je temi mo;

 Gb’ okan mi, Tire n’ise

 Ma gunwa nibe titi.


6. Gba ‘feran mi, Oluwa,

 Mo fi gbogbo re fun O;

 Gb’ emi papa; lat’ oni

 Ki ‘m’ je Tire titi lai. Amin.



 Yoruba Hymn  APA 384 - Gba aiye mi, Oluwa

This is Yoruba Anglican hymns, APA 384- Gba aiye mi, Oluwa . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post