Yoruba Hymn APA 437 - Jesu, ‘Wo oninure
APA 437
1. Jesu, ‘Wo oninure
Sin wa lo tabili Re;
Si f’onje orun bowa.
2. B’a ti kunle yi O ka,
Je k’a mo p’ o sunmo wa;
Si f’ ife nla Re han ni.
3. Gb’ a ba nf’ igbagbo wo O,
T’a si nsokun ese wa,
So aro wa di ayo.
4. Gb’ a tab a f’enu kan wain,
Ti nsapere eje Re,
M’okan wa kun fun ife.
5. Fa wa sibi iha Re,
Nibiti isun ni nsan,
Si we gbogbo ese nu.
6. Jo tu ide ese wa,
Si busi igbagbo wa
F’ alafia re fun wa.
7. Ma f’owo Re to wan so,
Tit’ ao fi de ‘bugbe Re,
N’ ile t’ o dara julo. Amin.
Yoruba Hymn APA 437 - Jesu, ‘Wo oninure
This is Yoruba Anglican hymns, APA 437- Jesu, ‘Wo oninure. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.
Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals