Yoruba Hymn APA 436 - Ojo Ko; ase na leyi

Yoruba Hymn APA 436 - Ojo Ko; ase na leyi

Yoruba Hymn  APA 436 - Ojo Ko; ase na leyi

APA 436

 1. Ojo Ko; ase na leyi;

 Mo f’ara mi fun nyin;

 E wo, mo f’ eje mi fun nyin,

 Lati ran nyin pada.


2. O di ‘nu ‘joba Baba mi,

 Ki mto tun ban yin mu;

 ‘Gbana ekun ko ni si mo,

 A o ma yo titi.


3. Titi l’a o ma je onje eyi

 K’ o to di igba na;

 Ka gbogb’ aiye l’ opolopo

 Y’o ma je, y’o ma mu.


4. ‘Bukun atorunwa y’o ma

 Wa lor’ awon t’ o nje;

 Ngo gbe or’ ite Baba mi

 Ma pes’ aye fun won.


5. Sugbon nisisiyi, ago

 Kikoro l’ em’ o mu,

 Emi o mu nitori nyin,

 Ago rora iku.


6. E ko le mo banuje mi,

 E ko ti r’ogo mi;

 Sugbon e ma s’eyi titi,

 K’e ma fir anti mi. Amin.Yoruba Hymn  APA 436 - Ojo Ko; ase na leyi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 436- Ojo Ko; ase na leyi. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post