Yoruba Hymn APA 527 - Olorun, awa fe

Yoruba Hymn APA 527 - Olorun, awa fe

Yoruba Hymn  APA 527 - Olorun, awa fe

APA 527

 1. Olorun, awa fe

 Ile t’ola Re wa;

 Ayo ibugbe Re

 Ju gbogbo ayo lo.


2. Ile adura ni,

 Fun awa omo Re;

 Jesu, O wa nibe,

 Lati gbo ebe wa.


3. Awa fe ase Re,

 Kil’ o dun to l’ aiye;

 Nib’ awon oloto,

 Nri O nitosi won.


4. Awa fe oro Re,

 Oro alafia;

 T’itunu at’ iye,

 Oro ayo titi.


5. A fe korin anu,

 T’a nri gba l’aiye yi;

 Sugbon awa fe mo

 Orin ayo t’orun.


6. Jesu, Oluwa wa,

 Busi ’fe wa nihin;

 Mu wa de ’nu ogo,

 Lati yio O titi. Amin.Yoruba Hymn  APA 527 - Olorun, awa fe

This is Yoruba Anglican hymns, APA 527- Olorun, awa fe. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post