Yoruba Hymn APA 528 - Gbogbo enyin ti ngbe aiye

Yoruba Hymn APA 528 - Gbogbo enyin ti ngbe aiye

Yoruba Hymn  APA 528 - Gbogbo enyin ti ngbe aiye

APA 528

 1. Gbogbo enyin ti ngbe aiye,

 E f’ayo korin s’Oluwa;

 F’ iberu sin, e yin l’ogo,

 E wa s’odo Re, k’ e si yo.


2. Oluwa, On no Olorun,

 Laisi ’ranwo wa, O da wa;

 Agbo Re ni wa, O mbo wa:

 O si fi wa s’agutan Re.


3. Nje, f’iyin wo ile Re wa,

 F’ ayo sunmo agbala Re;

 Yin, k’e bukun oruko Re,

 ’Tori o ye be lati se.


4. Ese! Rere l’ Olorun wa,

 Anu Re, o wa titi lai;

 O to Re ko figbakan ye,

 O duro lat’ iran-de-ran. Amin.Yoruba Hymn  APA 528 - Gbogbo enyin ti ngbe aiye

This is Yoruba Anglican hymns, APA 528- Gbogbo enyin ti ngbe aiye. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post