Yoruba Hymn APA 557 - Emi ’ba n’ egberun ahon

Yoruba Hymn APA 557 - Emi ’ba n’ egberun ahon

 Yoruba Hymn  APA 557 - Emi ’ba n’ egberun ahon

APA 557

1. Emi ’ba n’ egberun ahon,

 Fun ’yin Olugbala,

 Ogo Olorun Oba mi,

 Isegun ore Re.


2. Jesu t’O s’eru wa d’ayo,

 T’O mu banuje tan;

 Orin ni l’ eti elese,

 Iye at’ ilera.


3. O segun agbara ese,

 O da onde sile;

 Eje Re le w’ eleri mo,

 Eje Re seun fun mi.


4. O soro, oku gb’ohun Re;

 O gba emi titun;

 Onirobinuje y’ayo,

 Otosi si gba gbo.


5. Odi, e korin iyin Re;

 Aditi, gbohun Re;

 Afoju, Olugbala de,

 Ayaro, fo f’ayo.


6. Baba mi at’ Olorun mi,

 Fun mi n’iranwo Re;

 Kin le ro ka gbogbo aiye,

 Ola Oruko Re. Amin.



Yoruba Hymn  APA 557 - Emi ’ba n’ egberun ahon

This is Yoruba Anglican hymns, APA 557-  Emi ’ba n’ egberun ahon. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post