Yoruba Hymn APA 558 - Wo, owon Olurapada

Yoruba Hymn APA 558 - Wo, owon Olurapada

Yoruba Hymn  APA 558 - Wo, owon Olurapada

APA 558

 1. ’Wo, owon Olurapada,

 A fe ma gburo Re;

 Ko s’ orin bi oruko Re,

 T’o le dun t’ abo re.


2. A! a ba le ma gbohun Re!

 L’ anu soro si wa;

 Nin’ Alufa wa l’a o yo,

 Melkisedek giga.


3. Jesu ni y’o se orin wa,

 Nigbat’ a wa l’aiye;

 A o korin ife Jesu,

 ’Gba nkan gbogbo baje.


4. Nigba ’ba yo soke lohun,

 Pelu ’jo, eni Re;

 ’Gbana a o korin kikan,

 Krist ni y’o j’ orin wa. Amin.Yoruba Hymn  APA 558 - Wo, owon Olurapada

This is Yoruba Anglican hymns, APA 558-  Wo, owon Olurapada. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post