Yoruba Hymn APA 556 - Fun anu to po b’iyanrin

Yoruba Hymn APA 556 - Fun anu to po b’iyanrin

Yoruba Hymn  APA 556 - Fun anu to po b’iyanrin

APA 556

 1. Fun anu to po b’iyanrin,

 Ti mo ngba l’ ojumo;

 Lati’odo Jesu Oluwa,

 Kil’ emi o fi fun?


2. Kini ngo fi fun Oluwa,

 Lat’inu okan mi?

 Ese ti ba gbogbo re je,

 Ko tile jamo nkan.


3. Eyi l’ohun t’emi o se,

 F’ohun t’O se fun mi;

 Em’o mu ago igbala,

 Ngo kepe Olorun.


4. Eyi l’ope ti mo le da,

 Emi osi, are;

 Em’o ma soro ebun Re,

 Ngo si ma bere si.


5. Emi ko le sin b’ o ti to,

 Nko n’ise kan to pe;

 Sugbon em’o sogo yi pe,

 Gbese ope mi po. Amin.Yoruba Hymn  APA 556 - Fun anu to po b’iyanrin

This is Yoruba Anglican hymns, APA 556-  Fun anu to po b’iyanrin. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post