Yoruba Hymn APA 583 - Otosi elese ni mi

Yoruba Hymn APA 583 - Otosi elese ni mi

 Yoruba Hymn  APA 583 - Otosi elese ni mi

APA 583

1. Otosi elese ni mi,

 Mo l’ore Alagbara kan,

 Olugbala l’oruko Re;

 Ife Tire ko nipekun.


2. O ri mo sina kakiri,

 O mu mi wo agbo Re wa,

 O fie je mimo ra mi,

 O si segun ota fun mi.


3. O mu okan mi yo wipe,

 Nisisiyi l’emi o wa

 Pelu Re l’ori ’te l’orun;

 Ore-ofe yi tip o to! Amin.Yoruba Hymn  APA 583 - Otosi elese ni mi

This is Yoruba Anglican hymns, APA 583-  Igbala ni, igbala ni. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post