Yoruba Hymn APA 584 - Enit’ O la ’ju afoju

Yoruba Hymn APA 584 - Enit’ O la ’ju afoju

 Yoruba Hymn  APA 584 - Enit’ O la ’ju afoju

APA 584

1. Enit’ O la ’ju afoju,

 Ti O mu ope gbon,

 At’ enit’ O da imole,

 Fun eni okunkun.


2. Enit’ O le fi agbara

 F’ awon olokunrun,

 Ti O si fie mi iye

 Fun awon t’o ti ku.


3. Eni fi ’dasile f’okan,

 T’O gb’ eni subu nde,

 T’O si pa ibinuje da

 S’ orin pelu iyin.


4. Wo Onisegun okan mi,

 Si O l’ awa nkorin,

 Titi aiye o fi d’ opin,

 Tire l’ ope o se. Amin. Yoruba Hymn  APA 584 - Enit’ O la ’ju afoju

This is Yoruba Anglican hymns, APA 584-  Enit’ O la ’ju afoju. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post