Yoruba Anglican Hymn Apa 18 - Baba, a tun pade l’oko Jesu

Yoruba Anglican Hymn Apa 18 - Baba, a tun pade l’oko Jesu

Yoruba Hymn Apa 18 - Baba, a tun pade l’oko Jesu

APA 18

 1. Baba, a tun pade l’oko Jesu,

 A si wa teriba lab’ ese Re:

 A tun fe gb’ ohun wa soke si O

 Lati wa anu, lati korin ’yin.

 

2. A yin O fun itoju ’gbagbogbo,

 Ojojumo l’ a~o ma rohin ’se re;

 Wiwa laye wa, anu Re ha ko?

 Apa Re ki o fi ngba ni mora?


3. O se ! a ko ye fun ife nla Re,

 A sako kuro lodo Re poju;

 Sugbon kikankikan ni O si npe;

 Nje, a de, a pada wa le, Baba.


4. Nipa oko t’ o bor’ ohun gbogbo,

 Nipa ife t’ o ta ’fe gbogbo yo,

 Nipa eje ti a ta fun ese,

 Silekun anu, si gbani si le. Amin.This is Yoruba Anglican Hymn Apa 18 - Baba, a tun pade l’oko Jesu. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post