Yoruba Anglican Hymn Apa 17 - L’ oju ale, ’gbat ’orun wo

Yoruba Anglican Hymn Apa 17 - L’ oju ale, ’gbat ’orun wo

 Yoruba Hymn Apa 17 - L’ oju ale, ’gbat ’orun wo

APA 14

 1. L’ oju ale, ’gbat ’orun wo,

 N won gbe abirun w’ odo Re:

 Oniruru ni aisan won,

 Sugbon nwon f’ ayo lo ’le won.


2. Jesu a de l’ oj’ ale yi,

 A sunmo, t’ awa t’ arun wa,

 Bi a ko tile le ri O,

 Sugbon a mo p’ O sunmo wa.


3. Olugbala, wo osi wa;

 Omi ko san, mi banuje,

 Omi ko ni ife si O,

 Ife elomi si tutu.


4. Omi mo pe, asan l’ aiye

 Beni nwon ko f’ aiye sile:

 Omi l’ ore ti ko se ’re,

 Benin won ko fi O s’ore.


5. Ko s’ okan ninu wa t’ o pe,

 Gbogbo wa si ni elese:

 Awon t’ o si nsin O toto

 Mo ara won ni alaipe.


6. Sugbon Jesu Olugbala,

 Eni bi awa n’ Iwo ’se:

 ’Wo ti ri ’danwo bi awa

 ’Wo si ti mo ailera wa.

 

7. Agbar’ owo Re wa sibe

 Ore Re si li agbara

 Gbo adura ale wa yi

 Ni anu, wo gbogbo wa san. Amin.

This is Yoruba Anglican Hymn Apa 17 - L’ oju ale, ’gbat ’orun wo. Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals.

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post