Yoruba Hymn APA 304 - Baba, b’ ife Re ni, lati

Yoruba Hymn APA 304 - Baba, b’ ife Re ni, lati

Yoruba Hymn  APA 304 -  Baba, b’ ife Re ni, lati

APA 304

 1. Baba, b’ ife Re ni, lati

 Du mi l’ ohun aiye,

 Sa je ki adura mi yi

 Goke de ite Re.


2. F’okan tutu, t’ope fun mi;

 Gba mi lowo kikun;

 Fun mi n’ ibukun or’ ofe;

 Si je ki nwa fun O.


3. K’ ero yip e, ’Wo ni temi

 Ma ba mi lo laiye;

 Pelu mi lona ajo mi,

 Si ba mi d’opin re. Amin.Yoruba Hymn  APA 304 -  Baba, b’ ife Re ni, lati

This is Yoruba Anglican hymns, APA 304- Baba, b’ ife Re ni, lati . Yoruba hymns are worship hymns used in the Anglican Church for all kinds of worship and services. It is known as Iwe orin mimo.

Hymns in the Anglican Communion are translated into different languages. In the Igbo language, we have Abu or Ekpere na Abu. In the English language, it is called Ancient and Modern or Church hymnals

Post a Comment (0)
Previous Post Next Post